Iwe Oro Inu Jagun JagunIwe Oro Inu Jagun JagunAuthor / Uploaded Adekunle Obas
ORO TO NGBENU JAGUN JAGUN 1. ASO OGUN PELU IBANTE ISENBAYE RIRE Aso obo Aso fuu Aso ara egungun Aso etu Aso kijipa Aso oke dudu abi pupa Awon aso ti an lo latifi re ibante abi aso ogun niyii , nitori awon aso yii dara daadaa won si ma nipon daadaa , Awon ologun abi jagun jagun aye igbayen abi awon olode awon aso ti won nlo fi re ibante abi aso ogun niyii Bawo ni an se nre aso yiii , orisirisi ibante abi aso ogun lo nbe daadaa sugbon taba fe re aso lasan fun ibante abi aso ogun tasi fe ta nkan mo lara , Akiyesi .. Gbogbo ise taba fe de mo ara ibante abi aso ogun ni won budo je eyii tafin owu dudu ati funfun we , otun mo si ( ikobere ) tiwon si je ogun tiwon ko ni eje telee , nitori awon ise kan wa obi adie ni won wa , adie opipi ni won gba , malu ni won n gba , obuko , sugbon ise taba mo wipe won ko ni eje la ma di mo ara awon nkan won yii , to ba je wipe a fe re aso lasan fun lati so di ibante fun ara wa abi aso ogun bayii la se se.... Epo apa tutu Epo iroko Epo igi nla Epo...