EWE ATI EGBO IWOSAN APA KINNI
EWE ATI EGBO IWOSAN APA KINNI EWE KUKUNDUKU, EWE ANAMO, (Ipomoea batata) 1. JEDIJEDI A o se lagbo pelu omi lasan. A ma mu ni aagasi kokan lemeta loju mo. 2. INAJIJO ARA TABI OMI GBIGBONA JIJO. A o lo isu idi ewe anamo a o ma file oju ibi ti nkan to jo eni na. 3. ITOJU OJU TOPON ATI TOWA OMI . A o ge isu anamo keekeke si inu omi leyi wakati kan a o mi fisi oju naa igba gbogbo. 4. KI ARA LE MA DAN DADA. A o gun ewe tabi isu anamo mose a o ma fiwe. 5. TITOJU ATI IDENA JEJERE A o re isu anamo tabi sise isu ati ewe re logbo a o ma mu a o si ma fiwe oju re ti o bati je jade. Mimu lemeta loju mo. 6. ILERA ALABOYUN ATI OYAN FUN OMO OWO. Jije anamo ni tutu fun alaboyun le kookan titi yo do bimo ati eyin omo Bibi fun eroja fitami A. 7. ARUN ITO SUGA ATI ATOGBE. Jije iyofun isu anamo tabi sise je fun eni na tabi jije ni tutu. A letter ma lo gbogbo e papo. Tori opo fibre to le ni 77% ti ki pare mo omi. 8. KI ARA MAJIPEPE Bi o se wa ni oke no 7. 9. ARA WIWU TABI ARA DI...