EWE ATI EGBO IWOSAN APA KINNI

EWE ATI EGBO IWOSAN APA KINNI



EWE KUKUNDUKU, EWE ANAMO,
(Ipomoea batata)


1. JEDIJEDI
A o se lagbo pelu omi lasan. A ma mu ni aagasi kokan lemeta loju mo.

2. INAJIJO ARA TABI OMI GBIGBONA JIJO.
A o lo isu idi ewe anamo a o ma file oju ibi ti nkan to jo eni na.

3. ITOJU OJU TOPON ATI TOWA OMI.
A o ge isu anamo keekeke si inu omi leyi wakati kan a o mi fisi oju naa  igba gbogbo.

4. KI ARA LE MA DAN DADA.
A o gun ewe tabi isu anamo mose a o ma fiwe.

5. TITOJU ATI IDENA JEJERE
A o re isu anamo tabi sise isu ati ewe re logbo a o ma mu a o si ma fiwe oju re ti o bati je jade. Mimu lemeta loju mo.

6. ILERA ALABOYUN ATI OYAN FUN OMO OWO.
Jije anamo ni tutu fun alaboyun le kookan titi yo do bimo ati eyin omo Bibi fun eroja fitami A.

7. ARUN ITO SUGA ATI ATOGBE.
Jije iyofun isu anamo tabi sise je fun eni na tabi jije ni tutu. A letter ma lo gbogbo e papo. Tori opo fibre to le ni 77% ti ki pare mo omi.

8. KI ARA MAJIPEPE
Bi o se wa ni oke no 7.

9. ARA WIWU TABI ARA DIDUN
A o fi atike anamo si omi a o ma fi le ibe to yo fi lo. Ewe tabi isu.

10. OGBE INU ATI ITA
A ma po iyefun anamo ni omitutu a o mamu a o ma fi si oju re. Ewe ati elubo re.

11. ARUN OKAN, APO EJE ATI EJE RIRU.
A o ma gbo ewe anamo ati sise mu ati ekan idi re ni gbogbo igba. 

12. IBA JEFUNJEFUN
A o ma gbo ewe anamo bi ti ti oke.

13. IKO IGBAYADIDUN BI OTUTU AYA 
A o ma gbo ewe anamo bi ti ti oke.
14. OGUN IRUN ATI AWO ARA 
A o ma fi iyefun anamo si omi a o ma fi pa irun tabi ara ni gbogbo igba. Ti abawon ara ati oju, ewe tabi isu anamo.

15. IGBE LILE TABI INU KIKUN
A o ma gbo ewe anamo mu. Tabi ki a semu ife kan lemeta lojumo.

16. EJE RIRU
A o gbo ewe anamo mu. Tabi ki a ma po iyefun re mu bi ogi.

17. JIJE EWE ATI EGBO ANAMO
A ma je ki a dena airomobi, yiyaradanu ati jije ki opolo ji pepe.
18. AWURE 
Ewe anamo, suga eyokan, eri agbado a o gun mo ose dudu a o ma fiwe ni idaji lojojumo.

19. AIRIORUNSUN ATI IPAYA
A o ma lo iyefun ati agbo anamo ni igba gbogbo tori eroja magnesiumu ti opo ni be.

Comments

Popular posts from this blog

EID-L-FITR

BERIAL CEREMONIES

The Head Light