ARE-OJE
Egungun yi sora re Egun bi eyin osi Egungun yi fura sirare Okuta bikaun osi Egungun makoja aye re Iyo loga awon yerupe Egungun yi mo iwo ara re Egungun bi Lebe si Tani je foju di Ladogba Ninu egungun. Ajobiewe akoni onijo ni Oga olokiti si ni Dasofunjo Ile gbogbo won Loje Ti o ni ogba oro. Ojetunde agbo ile Alagbaa Lo to wa. Se bi baba egungun ni Ile ti won se. Ba ba mo ki, Are-oje egungun Olori gbogbo areku jaye ni. Are-oje o! Ojelarinnaka o wa moju to Awon omo re ti nrin ihoho Woja yi. Omode iwoyi o naani a nwoso Reja mo, ekisa loku ti won wo. Are-oje o ! Ojekomologbon o wa mu atori Fun omo alainitiju ti nboju bora Wa atori na awon alawose ti won ba oje lojuje. Are-oje o! Ojerinde omo aku lodo ma fara kan omi. Igbori, Omo ku nile kodaa pon Oku eko awon ni ijagudu akara. E fakara bomode tagba Ki e fi Eko kowon logbon asa. Sebi odundun le ndaso fegun Ti ngbagere lara won. Are-oje o! Ke si, Are-ilu ko filu kowa lasa igbaye. Are-ilu ki opa bolu O nfi ok...