COMMON HERBS ONE(KUJEKUJE APARO)

COMMON HERBS ONE(KUJEKUJE APARO)

wibe - 09/02/2022 
 
Mollugo Nullicaulis Lam 
Kujekuje Aparo - Yoruba 
Narba - Hausa 
Naked stem chickened.  







1. Iko ati otutu A o se ewe kujekuje yi latike pelu atare. A o ma fin Simi ati ki a ma later lekokan lemeeta lojumo. 


2. Iko Awubi ati seje nimu. Bi atise ti iko ati tutu loke, be ni a o ti lo. 


3. Iba Jefujefu. A o lo ewe kujekuje yi pelu Alubosa Ayu, a o ma fi mu tea tabi eko gbigbona leemeta lojumo. 



4. Iba Apatisan. A o lo ewe kuje yi die mo milk tabi fifi alike ewe kujekuje so milk leemeta lojumo. 



5. Arun oju. A o ma fi omi ti a fun lati ara ewe kujekuje yi si ninu milk, a o ma man si oju naa ni gbogbo igba. 




6. Arun awoo. A o lo ewe kujekuje yi a o se ketepe (paste) si ara tabi ibi ti o ni abawon. Oowo ti yo ti yo fi tu oyun jade.

Comments

Popular posts from this blog

EID-L-FITR

BERIAL CEREMONIES

The Head Light